Kọrinti Kinni 9:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣebí ẹ mọ̀ pé gbogbo àwọn tí ń sáré ìje ni ó ń sáré, ṣugbọn ẹnìkan ṣoṣo níí gba ẹ̀bùn. Ẹ sáré ní ọ̀nà tí ẹ óo fi rí ẹ̀bùn gbà.

Kọrinti Kinni 9

Kọrinti Kinni 9:23-27