Kọrinti Kinni 7:32 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn mo fẹ́ rí i pé ẹ kò ní ìpayà kan tí yóo mú ọkàn yín wúwo. Ẹni tí kò bá ní iyawo yóo máa páyà nípa nǹkan Oluwa, yóo máa wá ọ̀nà láti ṣe ohun tí ó wu Oluwa.

Kọrinti Kinni 7

Kọrinti Kinni 7:27-40