Kọrinti Kinni 7:31 BIBELI MIMỌ (BM)

Kí àwọn tí ń lo dúkìá ayé máa lò ó láì dara dé e patapata. Nítorí bí ayé yìí ti ń rí yìí, ó ń kọjá lọ.

Kọrinti Kinni 7

Kọrinti Kinni 7:25-35