Kọrinti Kinni 7:30 BIBELI MIMỌ (BM)

Kí àwọn tí ń sunkún máa ṣe bí ẹni pé wọn kò sunkún. Kí àwọn tí ń yọ̀ máa ṣe bí ẹni pé wọn kò yọ̀. Kí àwọn tí ń ra nǹkan máa ṣe bí ẹni pé kì í ṣe tiwọn ni ohun tí wọ́n ní.

Kọrinti Kinni 7

Kọrinti Kinni 7:24-31