Kọrinti Kinni 7:33 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn ẹni tí ó bá gbeyawo yóo máa páyà nípa nǹkan ti ayé yìí, yóo máa wá ọ̀nà láti tẹ́ iyawo rẹ̀ lọ́rùn;

Kọrinti Kinni 7

Kọrinti Kinni 7:30-35