Kọrinti Kinni 7:26 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo rò pé ohun tí ó dára ni pé kí eniyan má ṣe kúrò ní ipò tí ó wà, nítorí àkókò ìpọ́njú ni àkókò yìí.

Kọrinti Kinni 7

Kọrinti Kinni 7:22-32