Kọrinti Kinni 7:27 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí o bá ti gbé iyawo, má ṣe wá ọ̀nà láti kọ aya rẹ. Bí o bá sì ti kọ aya rẹ, má ṣe wá ọ̀nà láti tún gbé iyawo.

Kọrinti Kinni 7

Kọrinti Kinni 7:25-30