Kọrinti Kinni 7:25 BIBELI MIMỌ (BM)

N kò ní àṣẹ kan láti ọ̀dọ̀ Oluwa láti pa fún àwọn wundia. Ṣugbọn mò ń sọ ohun tí mo rò gẹ́gẹ́ bí ẹni tí Oluwa ti ṣàánú fún, tí eniyan sì lè gbẹ́kẹ̀lé.

Kọrinti Kinni 7

Kọrinti Kinni 7:17-30