Kọrinti Kinni 7:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí ẹnikẹ́ni bá jẹ́ ẹni tí ó kọlà nígbà tí a pè é, kí ó má ṣe pa ilà rẹ̀ rẹ́. Bí ẹnikẹ́ni bá jẹ́ aláìkọlà nígbà tí a pè é, kí ó má ṣe kọlà.

Kọrinti Kinni 7

Kọrinti Kinni 7:14-27