Kọrinti Kinni 7:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Kí olukuluku máa gbé ìgbé-ayé rẹ̀ bí Oluwa ti yàn án fún un, kí ó sì wà ní ipò tí ó wà nígbà tí Ọlọrun fi pè é láti di onigbagbọ. Bẹ́ẹ̀ ni mò ń fi kọ́ gbogbo àwọn ìjọ.

Kọrinti Kinni 7

Kọrinti Kinni 7:13-23