Kọrinti Kinni 7:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí, ta ni ó mọ̀, bóyá ìwọ aya ni yóo gba ọkọ rẹ là? Tabi ta ni ó mọ̀, ìwọ ọkọ, bóyá ìwọ ni o óo gba aya rẹ là?

Kọrinti Kinni 7

Kọrinti Kinni 7:6-21