Kọrinti Kinni 7:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Ati a kọlà ni, ati a kò kọlà ni, kò sí èyí tí ó ṣe pataki. Ohun tí ó ṣe pataki ni pípa àwọn òfin Ọlọrun mọ́.

Kọrinti Kinni 7

Kọrinti Kinni 7:14-26