Kọrinti Kinni 4:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Kì í ṣe pé mo fẹ́ dójú tì yín ni mo fi ń kọ nǹkan wọnyi si yín, mò ń kìlọ̀ fun yín gẹ́gẹ́ bí àyànfẹ́ ọmọ mi ni.

Kọrinti Kinni 4

Kọrinti Kinni 4:11-18