Kọrinti Kinni 4:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí pé, ẹ̀ báà ní ẹgbẹrun àwọn olùtọ́ ninu Kristi, ẹ kò ní ju ẹyọ baba kan lọ. Nítorí ninu Kristi Jesu, èmi ni mo bi yín nípa ọ̀rọ̀ ìyìn rere.

Kọrinti Kinni 4

Kọrinti Kinni 4:8-16