Kọrinti Kinni 4:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n ń sọ̀rọ̀ burúkú sí wa, ṣugbọn àwa ń sọ̀rọ̀ ìwúrí. A di ohun ẹ̀sín fún gbogbo ayé. A di pàǹtí fún gbogbo eniyan títí di bí a ti ń sọ̀rọ̀ yìí.

Kọrinti Kinni 4

Kọrinti Kinni 4:4-15