Kọrinti Kinni 3:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Kí ẹnikẹ́ni má ṣe tan ara rẹ̀ jẹ. Bí ẹnìkan ninu yín bá rò pé òun gbọ́n ọgbọ́n ti ayé yìí, kí ó ka ara rẹ̀ sí òmùgọ̀ kí ó lè gbọ́n.

Kọrinti Kinni 3

Kọrinti Kinni 3:11-20