Kọrinti Kinni 3:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí agọ̀ ni ọgbọ́n ayé yìí lójú Ọlọrun. Nítorí ó wà ní àkọsílẹ̀ pé, “Ẹni tí ó mú àwọn ọlọ́gbọ́n ninu àrékérekè wọn.”

Kọrinti Kinni 3

Kọrinti Kinni 3:17-23