Kọrinti Kinni 3:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí ẹnikẹ́ni bá ba Tẹmpili Ọlọrun jẹ́. Ọlọrun yóo pa òun náà run. Nítorí mímọ́ ni Tẹmpili Ọlọrun, ẹ̀yin náà sì ni Tẹmpili Ọlọrun.

Kọrinti Kinni 3

Kọrinti Kinni 3:10-21