Kọrinti Kinni 12:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí etí bá sọ pé, “Èmi kì í ṣe ojú, nítorí náà èmi kò sí ninu ara,” kò wí pé kí ó má ṣe ẹ̀yà ara mọ́.

Kọrinti Kinni 12

Kọrinti Kinni 12:8-26