Kọrinti Kinni 12:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí gbogbo ara bá jẹ́ ojú, báwo ni yóo ti ṣe gbọ́ràn? Bí gbogbo ara bá jẹ́ etí, báwo ni yóo ti ṣe gbóòórùn?

Kọrinti Kinni 12

Kọrinti Kinni 12:8-24