Kọrinti Kinni 12:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí ẹsẹ̀ bá sọ pé, “Èmi kì í ṣe ọwọ́, nítorí náà èmi kò sí ninu ara,” èyí kò wí pé kì í tún ṣe ẹ̀yà ara mọ́.

Kọrinti Kinni 12

Kọrinti Kinni 12:9-18