Kọrinti Kinni 10:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn sibẹ inú Ọlọrun kò dùn sí ọpọlọpọ ninu wọn, nítorí ọpọlọpọ wọn ni wọ́n kú dànù káàkiri ninu aṣálẹ̀.

Kọrinti Kinni 10

Kọrinti Kinni 10:1-13