Kọrinti Kinni 10:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn nǹkan wọnyi jẹ́ àpẹẹrẹ fún wa, pé kí á má ṣe kó nǹkan burúkú lé ọkàn, gẹ́gẹ́ bí àwọn ti kó o lé ọkàn.

Kọrinti Kinni 10

Kọrinti Kinni 10:2-11