Kọrinti Kinni 10:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo wọn ni wọ́n mu omi ẹ̀mí kan náà, nítorí wọ́n mu omi tí ó jáde láti inú òkúta ẹ̀mí tí ó ń tẹ̀lé wọn. Òkúta náà ni Kristi.

Kọrinti Kinni 10

Kọrinti Kinni 10:1-14