Kọrinti Kinni 10:1-3 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Ẹ̀yin ará, ẹ má gbàgbé pé gbogbo àwọn baba wa ni wọ́n wà lábẹ́ ìkùukùu. Gbogbo wọn ni wọ́n la òkun kọjá.

2. Gbogbo wọn ni wọ́n ṣe ìrìbọmi ninu ìkùukùu ati ninu òkun, kí wọ́n lè di ọmọ ẹ̀yìn Mose.

3. Gbogbo wọn ni wọ́n jẹ oúnjẹ ẹ̀mí kan náà.

Kọrinti Kinni 10