Kọrinti Keji 8:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Kì í ṣe pé ó lókìkí nìkan ni, ṣugbọn òun ni ẹni tí gbogbo àwọn ìjọ yàn pé kí ó máa bá wa kiri nípa iṣẹ́ oore-ọ̀fẹ́ tí à ń ṣe fún ògo Oluwa ati láti fi ìtara wa hàn.

Kọrinti Keji 8

Kọrinti Keji 8:13-14-24