Kọrinti Keji 8:20 BIBELI MIMỌ (BM)

À ń ṣe èyí kí ẹnikẹ́ni má baà rí nǹkan wí sí wa nípa ọ̀nà tí à ń gbà ṣe ètò ti ẹ̀bùn yìí.

Kọrinti Keji 8

Kọrinti Keji 8:18-22