Kọrinti Keji 8:18 BIBELI MIMỌ (BM)

A rán arakunrin tí ó lókìkí ninu gbogbo àwọn ìjọ nítorí iṣẹ́ rẹ̀ nípa ìyìn rere pé kí ó bá a wá.

Kọrinti Keji 8

Kọrinti Keji 8:17-24