Kọrinti Keji 4:8 BIBELI MIMỌ (BM)

A ní oríṣìíríṣìí ìṣòro, ṣugbọn wọn kò wó wa mọ́lẹ̀; ọkàn wa ń dààmú, ṣugbọn a kò ṣe aláìní ìrètí.

Kọrinti Keji 4

Kọrinti Keji 4:3-17