Kọrinti Keji 4:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn bí ìkòkò amọ̀ ni àwa tí ìṣúra yìí wà ninu wa rí, kí ó lè hàn gbangba pé Ọlọrun ni ó ní agbára tí ó tóbi jùlọ, kì í ṣe àwa.

Kọrinti Keji 4

Kọrinti Keji 4:1-11