Kọrinti Keji 4:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí Ọlọrun tí ó ní kí ìmọ́lẹ̀ tàn láti inú òkùnkùn, òun ni ó tan ìmọ́lẹ̀ sí ọkàn wa, kí ìmọ́lẹ̀ ìmọ̀ ògo Ọlọrun lè tàn sí wa ní ojú Kristi.

Kọrinti Keji 4

Kọrinti Keji 4:3-7