Kọrinti Keji 4:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí kì í ṣe nípa ara wa ni à ń waasu. Ẹni tí à ń waasu rẹ̀ ni Jesu Kristi pé òun ni Oluwa. Iranṣẹ yín ni a jẹ́, nítorí ti Kristi.

Kọrinti Keji 4

Kọrinti Keji 4:3-8