Kọrinti Keji 4:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn eniyan ń ṣe inúnibíni sí wa, ṣugbọn Ọlọrun kò fi wá sílẹ̀. Wọ́n gbé wa ṣubú, ṣugbọn wọn kò lè pa wá.

Kọrinti Keji 4

Kọrinti Keji 4:1-14