Kolose 2:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó sì ti ṣe yín ní pípé ninu rẹ̀. Òun níí ṣe orí fún gbogbo àwọn ẹ̀mí ojú ọ̀run, ìbáà ṣe ìjọba tabi àwọn aláṣẹ.

Kolose 2

Kolose 2:9-11