Kolose 2:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí pé ninu Kristi tí ó jẹ́ eniyan ni ohun tí Ọlọrun fúnrarẹ̀ jẹ́, ń gbé lẹ́kùn-únrẹ́rẹ́.

Kolose 2

Kolose 2:2-16