Kolose 2:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Ninu Kristi yìí ni a ti kọ yín nílà, kì í ṣe ilà tí a fi ọwọ́ kọ nípa gígé ẹran-ara kúrò, ṣugbọn ilà ti Kristi;

Kolose 2

Kolose 2:4-20