Johanu 15:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí ẹ bá ń gbé inú mi, tí ọ̀rọ̀ mi ń gbé inú yín, ẹ óo bèèrè ohunkohun tí ẹ bá fẹ́, ẹ óo sì rí i gbà.

Johanu 15

Johanu 15:6-16