Johanu 15:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Báyìí ni ògo Baba mi yóo ṣe yọ, pé kí ẹ máa so ọpọlọpọ èso. Bẹ́ẹ̀ ni ẹ óo ṣe jẹ́ ọmọ-ẹ̀yìn mi.

Johanu 15

Johanu 15:1-11