Johanu 15:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí ẹnikẹ́ni kò bá gbé inú mi, a óo jù ú sóde bí ẹ̀ka, yóo sì gbẹ; wọn óo mú un, wọn óo sì fi dáná, yóo bá jóná.

Johanu 15

Johanu 15:2-8