Jeremaya 51:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìwọ ni mo fi lu tọkunrin tobinrin pa,ìwọ ni mo fi lu tọmọde, tàgbà pa,ìwọ ni mo sì fi run àwọn ọdọmọkunrin ati ọdọmọbinrin.

Jeremaya 51

Jeremaya 51:18-30