Jeremaya 51:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìwọ ni mo fi lu ẹṣin ati ẹni tí ń gùn ún pa;ìwọ ni mo fi wó kẹ̀kẹ́ ogun ati àwọn tí ń bẹ ninu wọn.

Jeremaya 51

Jeremaya 51:12-31