Jeremaya 51:20 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ìwọ ni òòlù ati ohun ìjà mi:ìwọ ni mo fi wó àwọn orílẹ̀-èdè wómúwómú,ìwọ ni mo sì fi pa àwọn ìjọba run.

Jeremaya 51

Jeremaya 51:12-29