Ìwọ ni mo fi pa olùṣọ́-aguntan ati agbo ẹran rẹ̀ rẹ́,ìwọ ni mo fi run àgbẹ̀ ati àwọn alágbàro rẹ̀,ìwọ ni mo fi ṣẹ́ apá àwọn gomina ati ti àwọn olórí ogun.”