Jeremaya 23:7 BIBELI MIMỌ (BM)

“Nítorí náà àkókò kan ń bọ̀, tí wọn kò ní máa búra ní orúkọ OLUWA tí ó kó àwọn ọmọ Israẹli jáde kúrò ní ilẹ̀ Ijipti mọ́,

Jeremaya 23

Jeremaya 23:1-15