Jeremaya 23:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Juda yóo rí ìgbàlà ní ìgbà tirẹ̀, Israẹli yóo sì wà láìléwu. Orúkọ tí a óo máa pè é ni ‘OLUWA ni òdodo wa.’

Jeremaya 23

Jeremaya 23:1-16