Jeremaya 23:38 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn bí ẹ bá mẹ́nu ba “Ẹrù OLUWA,” lẹ́yìn tí mo ti ranṣẹ si yín pé ẹ kò gbọdọ̀ mẹ́nu bà á mọ́,

Jeremaya 23

Jeremaya 23:31-40