Jeremaya 23:39 BIBELI MIMỌ (BM)

tìtorí rẹ̀, n óo sọ yín sókè, n óo sì gbe yín sọnù kúrò níwájú mi, àtẹ̀yin, àtìlú tí mo fi fún ẹ̀yin, ati àwọn baba ńlá yín.

Jeremaya 23

Jeremaya 23:36-40