Jeremaya 20:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Kí olúwarẹ̀ dàbí àwọn ìlú tí OLUWA parun láìṣàánú wọn.Kí ó gbọ́ igbe lówùúrọ̀,ati ariwo ìdágìrì lọ́sàn-án gangan.

Jeremaya 20

Jeremaya 20:13-18