Jeremaya 20:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Ègún ni fún ẹni tí ó yọ̀ fún baba mi,tí ó sọ fún un pé,“Iyawo rẹ ti bí ọmọkunrin kan fún ọ,tí ó mú inú rẹ̀ dùn.”

Jeremaya 20

Jeremaya 20:5-17