Jeremaya 20:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Ègún ni fún ọjọ́ tí a bí mi,kí ọjọ́ tí ìyá mi bí mi má jẹ́ ọjọ́ ayọ̀.

Jeremaya 20

Jeremaya 20:4-17